Moki gbogbo omo egbe olorire yioo(ONAMILA) lase olohun. Ona konidimo gbogbowa o AMIN
ise nla ni iseyije, papajulo fun idojuko ipenija ati isoro omoniyan, bi ide aye, igbekun ota ati bebelo.
Ise atude ituwo awon agba arobi agbelepota ti ona finsi kiakia ni iseyi je. Eje ki alo gbiyanjue wo👇👇👇👇👇
Yepe idi aro,tobadi aro kutukutu, aolosi idi aro onigi, aofi obe(knife) bu yepe idi arona ni ona meteta, aowalomo epo obo ati egbo tude, ati arigisegi ti omowa ninure, aolowon kunna daada aopomo ose eyikeyi, aowa bu iyo(salt) si oju igbin nla kan, tobatinyo omi aofi omi igbina pomo iyo oju e yen po osena daada, aowaseseko osena sinu igba sanponna(igba onikoko) aogbe osena pamofun ojo meya ti ojukankan kogbodo ri,
Leyin ojo keta aomofi osenawe lalale ati idaji
Kosi bi ogun na sele lemoya to, pelu ogo olohin itusile made, ti wonba nro ero aburu tabi asasi buruku siyan oma pada sori onibi ni, benni gbogbo ona todi pata lomasi lesekese
(Gbiyanju lati bere nkan tioba yeo labe comment ati idupe)
ONAMILA KONIBAJE OOOOOO
Comments