Ejekiagbiyanju osole yi kiakia kiawawo titobi olohun lara tewetegbo
ISENARE
Alangba adaripon kan,,Epo obo die,,,imi Ojo die,,atare pelu ikoko tuntun kekere kan ao du eje alangba yi sori isasun yi ao wa GBE alanga ti adu yi le epo obo ye ati imi ojo Lori ao Jo papo mo atare ao wa fi po ose ninu isasun naa ao fi abere oporo kan gun ose yen larin ,,ninu isasun yen naa ni ati malo Ogun yen kiato po lose, ....NB...lojo ti aba koko we oseyi ti aba WO motor conductor koni gbowo lowo wa omatun bere pe Elo ni change ti amagba ni .kia gba owo naa lowore tori ise na ti bere ise
بإذن الله
Comments