ETO EGBE ONAMILA 2022

 

AKU DEDE ASIKO YII
AKI GBOGBOWA KU ODUN OO,EMIWA YIOSE OPO ODUN LAYE AMIN

afi asikoyi dupe lowo gbogbo omo egbe YAO patapata fun adutoti yin lori AWON AAEYORI WA ti odun 2021, gbogbo omo egbe laki lapapo oo,olohun koni fi ibinure tuwa ka ooo,amin,leyin na,eyini lati se ILAKALA awon eto eyiti anifun odun yii,gegebi etimope bayi lasemonse lododun,idi niyi ti afi nfi asikoyi kede awon eto tuntun eyiti aomosisele lori fun odun 2021 yii.

LAKOKO_gbogbowa lamope onamila je egbe iba ara enisepo latari mimo pese ohun imu aye derun funrawa,eyi lofa tofijepe ilana wa yato gedegbe pupo,bedeni eyini afin fun pese ami idanimo funrawa tiamosi (APLLICANT CODE) latilefi da ojulowo arawa mo bedeni amo wipe bi asense eto lori afefe benaani anse eto lojukoroju (online program and live program) afojusun wa po pupo fun egbe yi,tori wipe awa kiise egbe ilura enini jibiti tabi egbe imo tara eninikan rara, anse etowa pelu ohunti yiomu irorun ba arawa atiba awon tontelewa lapapo(MEMBERS) eto eyiti awafese ilakale re funti odunyi lari gegebi ilana ti yiomu irorun ati idagbasoke(improvement) ba gbogbowa....

Awan rowa latile se awon amulo awon eto na ati lati tele awon ilana tiase alakaale re naa.

1)owo idarapo mo ojulowo onamila ati owo nonba idanimo(form and code fee) koyi pada #2,000 naani ,amo ayipada maba laipe yii latari awon nkan ti afefikun awon etowa

2)sise awon etowa yiomo lo gegebi tele,bedeni ti awon igbimo(admins) yiomo se funwa ni gbogbo igba.

3)ipade ojukoroju wa yiobere ni osu keji ,bedeni eyije ifojukan oju ti yiomu ilosiwaju ba gbogbowa,tori aomose ifilole awon ohun tuntun funrawa,ti ipade yiowaye ni ipinle wonyi lodunyi (lagos state,oyo state, osun state,kwara state,ati ogun state)

4)eko ori afefe wakun awon etowa paapa,leyiti awon eko na je ilana tiopeka pupo tosije eko iwulo funrawa,benni ekoyi ti bere __ti aosi tun fi awom eko miran kun(aomose alaye ni kikun funrawa siwaju sii...)

5)aonifi ayegba omo egbe tikoni amiidanimo lati dasi eto kankan ninu egbe onamila lodunyii, __tori agbagbo wipe awon tikoni ami idanimo leko ijamba ati ipalara wole,latari aini iforukowon sile ati ami ibugbewon sile (details) lodowa,wayio kosi aye fun kanda ninu iresii wa(third party)-(outsider).

6)aofi kun awon igbimo wa pelu ,eyi lafese latile mu egbe yi tesiwaju sii,latara awon igbimo tafeyan,bedeni awon igbimo yi yiowa lati inu omo egbe toni ami idanimo,ati eyiti otiko eko tewe tegbo lodowa(ORISUN EKO NIPA ISEGUN GROUP).

7)eto olododun wa eyiti amonse lati se ise imu ilosiwaju ba arawa(IRAPADA OGO/live changes program)yiowaye pelu ifowo sowopo arawa latise ise eyiti aolofun ibokuro ajaga ati idojuko aironalo funrawa lodunyi,tori agbagbo wipe ti ogun batikuro ninu aye eda,dandan ni kiori onalo,eto yi yiowaye laipe ti aose salaye lekunrere funrawa siwajuu sii.

8)eto card idanimo wa(ID card yiojade fun gbogbo omo egbe eyiti oni ami idanilo lodunyii,eyi alemomu jade lati lemofise afihan arawa nigboro wipe ogidi omo egbe onamila niwa....

9)awon ise ti aomogba wole lodunyi yiomo waye lati odo arawa ati lati odo awon ojogbon nikan, leyiti aonigba fun enikeni lati fi ise tiope tabi fi ise ipalara sile rara,onamila kiise egbe gbarogbudu rara,bi kiise egbe iwa ilosiwaju omo niyan.

10)ise ifirinle egbe wa ni ipinle kokan je eyiti aosisele lori lodunyii,lati da arawa mo ni ilu tiawa ati latile mo se ikojo arawa nibi eyikeyi eto tabafese nipinle naa.

WAYIO_alerope awon etowayi je nkan ti nifesii?? __tobaribe anfe ifowosowpo yin lori egbe yi,kiebawa se igbelaruge re siwajuu sii,tori ifowosowopo yin pelu wa lolemu ilosiwaju ba egbe Onamila ,ti awana defin da gbogbo omo egbe loji wipe aoni bayin lojuje rara(disappoint) lodunwon igbati eyina bati duro tiwa ....,.

AFIKUN
ohun rere toyato gedegbe nbo lona funwa ninu ileyi o,,looto kosi nini awon etowa amo ohunti yiomo muwa ni ilosiwaju ni pelu ayelura wa(aose alaye ni kikun ti etowa batin debe)

ONAMILA KONI BAJE OOO

Fun ibere_2348143027867



Comments